Friday 27 January 2023
Friday of week 3 in Ordinary Time
Compline (Night Prayer)
(today)
The Compline after First or Second Vespers of a Sunday may be substituted for the Compline of a weekday.
________
INTRODUCTION
Olúwa, wá ràn wá ló̩wó̩.
Olúwa, yára láti ràn wá ló̩wó̩.
Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩
àti fún È̩mí Mímó̩.
Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,
o ń be̩ nísinsìnyí,
bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo
ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.
INTRODUCTION
God, come to my assistance.
Lord, make haste to help me.
Glory to the Father and to the Son,
and to the Holy Spirit:
as it was in the beginning, is now,
and will be for ever. Amen. Alleluia.
________
Examination of Conscience
This is an excellent moment for an examination of conscience. In a communal celebration of Compline, one of the penitential acts given in the Missal may be recited.
________
Hymn
Now that the daylight dies away,
By all thy grace and love,
Thee, Maker of the world, we pray
To watch our bed above.
Let dreams depart and phantoms fly,
The offspring of the night,
Keep us, like shrines, beneath thine eye,
Pure in our foe’s despite.
This grace on thy redeemed confer,
Father, co-equal Son,
And Holy Ghost, the Comforter,
Eternal Three in One.
Hymn
Now that the daylight dies away,
By all thy grace and love,
Thee, Maker of the world, we pray
To watch our bed above.
Let dreams depart and phantoms fly,
The offspring of the night,
Keep us, like shrines, beneath thine eye,
Pure in our foe’s despite.
This grace on thy redeemed confer,
Father, co-equal Son,
And Holy Ghost, the Comforter,
Eternal Three in One.
________
Psalm 87 (88)
Àdúrà e̩ni tó wà nínú ìdùbúlè̩ àìsàn.
Olúwa O̩ló̩run mi, mo ké pè Ó̩ lóòjó̩ fún ìrànló̩wó̩, mo dárò lóru níwájú ù Re̩.
Olúwa O̩ló̩run mi, mo kígbe pè Ó̩ ló̩sàn-án,
Mo dárò lóru níwájú Re̩;
Jé̩ kí àdúrà mi dé ò̩dò̩ Re̩,
fetísí igbe mi.
Nítorí è̩mí mi ti kún fún ìbànújé̩,
ayé mi sì ti dé etí bèbè isà-òkú,
a ti kà mi kún èrò ibojì,
ó ti tán mó̩ mi!
Wó̩n s̩à mí tì pè̩lú àwo̩n òkú,
bí e̩ni tí a ti pa, tó wà ní sàréè,
bí àwo̩n tí Ìwo̩ kò rántí mó̩,
bí àwo̩n tó ti so̩nù kúrò ló̩wó̩ ò̩ Re̩.
Ìwo̩ fi mí sí ìsàlè̩ ilè̩ jínjìn,
nínú òkùnkùn, nínú ò̩gbun;
ìbínú Re̩ wúwo lórí mi,
Ìwo̩ sì ń rò̩jò ìbínú lé mi lórí,
Ìwo̩ ti mú àwo̩n e̩le̩gbé̩ mi jìnnà sí mi,
O ti so̩ mi di ohun ìríra fún wo̩n;
a ti sé mi mó̩lé, n kò lè jáde,
ojú mi ti rè̩wè̩sì nínú ìnira.
Mo ké pè Ó̩, Olúwa, ní gbogbo o̩jó̩,
Mo na o̩wó̩ mi sí O̩.
Ìwo̩ ha í s̩e is̩é̩ ìyanu fún àwo̩n òkú bí?
Ǹjé̩ òkú lè dìde yìn Ó̩ lógo bí?
Ǹjé̩ a lè sò̩rò̩ ifé̩ Re̩ ní isà-òkú,
tàbí ìròyìn òtító̩ Re̩ ní ilè̩ ègbé?
Ǹjé̩ wó̩n mo̩ is̩é̩ ńlá Re̩ níbi òkùnkùn,
tàbí òtító̩ Re̩ ní ilè̩ ìgbàgbé?
Mó ké pè Ó̩, Olúwa
Àdúrà mi dé ò̩dò̩ Re̩ ní òwúrò̩;
èés̩e tí O fi o̩wó̩ ró̩ è̩mí mi sé̩yìn,
tí O fi ojú pamó̩ jìnnà réré sí mi?
Olóríburúkú tí ń kú lo̩ láti ìgbà èwe mi,
mo ti farada ìbè̩rù Re̩, ó ti sú mi;
ìbè̩rù Re̩ wúwo lórí mi,
ojo Re̩ ti so̩ mi di e̩ni asán.
Wó̩n há mi mó̩ bí omi ní gbogbo o̩jó̩,
Wó̩n sé mi mó̩ níhà gbogbo.
Ìwo̩ mú ò̩ré̩ àti ojúlùmò̩ jìnnà sí mi,
Òkùnkùn ti di e̩nikejì mi!
Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩
àti fún È̩mí Mímó̩.
Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,
o ń be̩ nísinsìnyí,
bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo
ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.
Olúwa O̩ló̩run mi, mo ké pè Ó̩ lóòjó̩ fún ìrànló̩wó̩, mo dárò lóru níwájú ù Re̩.
Psalm 87 (88)
The prayer of one gravely ill
“This is your hour; this is the reign of darkness” (Lk 22:53).
Day and night I cry to you, my God.
Lord my God, I call for help by day;
I cry at night before you.
Let my prayer come into your presence.
O turn your ear to my cry.
For my soul is filled with evils;
my life is on the brink of the grave.
I am reckoned as one in the tomb:
I have reached the end of my strength,
like one alone among the dead;
like the slain lying in their graves;
like those you remember no more,
cut off, as they are, from your hand.
You have laid me in the depths of the tomb,
in places that are dark, in the depths.
Your anger weighs down upon me:
I am drowned beneath your waves.
You have taken away my friends
and made me hateful in their sight.
Imprisoned, I cannot escape;
my eyes are sunken with grief.
I call to you, Lord, all the day long;
to you I stretch out my hands.
Will you work your wonders for the dead?
Will the shades stand and praise you?
Will your love be told in the grave
or your faithfulness among the dead?
Will your wonders be known in the dark
or your justice in the land of oblivion?
As for me, Lord, I call to you for help:
in the morning my prayer comes before you.
Lord, why do you reject me?
Why do you hide your face?
Wretched, close to death from my youth,
I have borne your trials; I am numb.
Your fury has swept down upon me;
your terrors have utterly destroyed me.
They surround me all the day like a flood,
they assail me all together.
Friend and neighbour you have taken away:
my one companion is darkness.
Glory to the Father and to the Son,
and to the Holy Spirit:
as it was in the beginning, is now,
and will be for ever. Amen.
Day and night I cry to you, my God.
Psalm-Prayer
Lord Jesus, redeemer of all and author of our salvation, for us you went down to the realm of death and became free of death. Hear the prayers of your family and lift us from our slavery to evil, that we may be redeemed by you and see your Father’s glory.
Or:
Lord Jesus Christ, you chose to suffer and be overwhelmed by death in order to open the gates of death in triumph. Stay with us to help us on our pilgrimage; free us from all evil by the power of your resurrection. In the company of your saints, and constantly remembering your love for us, may we sing of your wonders in our Father’s house.
________
Scripture Reading
(Jeremáyà 14:9)
Ìwo̩ wà láàrín wa, Olúwa, orúko̩ ò̩ Re̩ ni a fi ń pè wá. Má s̩e kò̩ wá sílè̩! Olúwa Ó̩ló̩run wa.
Scripture Reading
(Jeremiah 14:9)
Lord, you are in our midst, we are called by your name. Do not desert us, O Lord our God!
________
Short Responsory
Ní o̩wó̩ Re̩, Olúwa, ni mo fi è̩mí mi lé.
– Ní o̩wó̩ Re̩, Olúwa, ni mo fi è̩mí mi lé.
Ìwó̩ ti rà wá padà, Olúwa O̩ló̩run olótìító̩.
– Ní o̩wó̩ Re̩, Olúwa, ni mo fi è̩mí mi lé.
Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩ àti fún È̩mí Mímó̩.
– Ní o̩wó̩ Re̩, Olúwa, ni mo fi è̩mí mi lé.
Short Responsory
Into your hands, Lord, I commend my spirit.
– Into your hands, Lord, I commend my spirit.
You have redeemed us, Lord God of truth.
– Into your hands, Lord, I commend my spirit.
Glory to the Father and to the Son and to the Holy Spirit.
– Into your hands, Lord, I commend my spirit.
________
Canticle
Nunc Dimittis
Krístì ni ìmó̩lè̩ àwo̩n orílè̩ èdè àti ògo Ísráé̩lì
Gbà wá, Olúwa, nígbà tí a bá wà lójúfò, dáàbò bò wá nígbà tí a bá ń sùn; jé̩ kí á lè má a wà ní ìs̩ó̩nà pè̩lú Krístì, kí á sì lè sinmi pè̩lú Rè̩ ní àlàáfíà.
Nísisìyí, Olúwa mi, ó té̩ mi ló̩rùn
kí Ìwo̩ jé̩ kí ìránńs̩é̩ Re̩ máa lo̩ ní àlàáfíà;
gé̩gé̩ bí ò̩rò̩ Re̩.
Nítorí ojú mi ti rí ìgbàlà Re̩
tí Ìwo̩ ti pèsè fún gbogbo énìyàn láti rí,
ìmó̩lè̩ tí yóò tàn sí àwo̩n orílè̩-èdè lára
àti ogo àwo̩n èníyàn Rè̩ Ísráé̩lí.
Ògo ni fún Baba àti fún O̩mo̩
àti fún È̩mí Mímó̩.
Bí ó ti wà látètèkó̩s̩e,
o ń be̩ nísinsìnyí,
bé̩è̩ ni ó sì máa rí nígbà gbogbo
ayé àìnípè̩kun. Àmín. Alelúyà.
Gbà wá, Olúwa, nígbà tí a bá wà lójúfò, dáàbò bò wá nígbà tí a bá ń sùn; jé̩ kí á lè má a wà ní ìs̩ó̩nà pè̩lú Krístì, kí á sì lè sinmi pè̩lú Rè̩ ní àlàáfíà.
Canticle
Nunc Dimittis
Christ is the light of the nations and the glory of Israel
Protect us, Lord, as we stay awake; watch over us as we sleep; that awake, we may keep watch with Christ, and asleep, rest in his peace.
Lord, now you let your servant go in peace;
your word has been fulfilled.
My own eyes have seen the salvation
which you have prepared in the sight of every people:
a light to reveal you to the nations
and the glory of your people Israel.
Glory to the Father and to the Son,
and to the Holy Spirit:
as it was in the beginning, is now,
and will be for ever. Amen.
Protect us, Lord, as we stay awake; watch over us as we sleep; that awake, we may keep watch with Christ, and asleep, rest in his peace.
________
E̩ jé̩ k’á gb’àdúrà.
O̩ló̩run Olódùmarè, dákun fún wa lóore-ò̩fé̩,
Kí a lè dàpò̩ mó̩ O̩mo̩ ò̩ Re̩ kan s̩os̩o pè̩lú ìgbàgbó̩,
E̩ni tó joró ikú tí a sì sín sínú ibojì
Kí a lè tún jí pè̩lú Rè̩ nínú ìyè tuntun,
E̩ni tó wà tó sì ń jo̩ba láé àti láéláé.
Àmín.
Let us pray.
All-powerful God,
keep us united with your Son
in his death and burial
so that we may rise to new life with him,
who lives and reigns for ever and ever.
Amen.
________
Kí Olúwa fún wa ní ìdè̩ra lóru yìí àti ìgbè̩yìn tí ó dára.
Àmín.
May the all-powerful Lord grant us a restful night and a peaceful death.
Amen.
________
Marian Anthem
Alma Redemptoris Mater
Mother of Christ! Hear thou thy people’s cry,
Star of the deep, and portal of the sky!
Mother of him who thee from nothing made,
Sinking we strive, and call to thee for aid:
Oh, by that joy which Gabriel brought to thee,
Thou Virgin first and last, let us thy mercy see.
Copyright © 1996-2022 Universalis Publishing Limited: see http://www.universalis.com. Scripture readings from the Jerusalem Bible are published and copyright © 1966, 1967 and 1968 by Darton, Longman & Todd, Ltd and Doubleday, a division of Random House, Inc, and used by permission of the publishers. Text of the Psalms: Copyright © 1963, The Grail (England). Used with permission of A.P. Watt Ltd. All rights reserved.